Àwọn èdè
From Wikipedia
BELLO ADIRAT KÍKÉLOMO
ÀWON ÈDÈ ÀTI ÈKÓ ÌMÒ ÈDÈ
Èdè ni ìlànà kan pàtàkì tó jé gbòógì tí óní ètò tí ó ń gbé kalè yálà láti ronú, kédùn ní ilé ayé. Èdè tún jé àkójopò ìró tí o ní ètò àti gbígbé ìró jáde. Bí a se mò ní àwùjo àwon ènìyàn sí àwon eranko ni ìsesí, isòròsí àti òrò àsogbà èdè tó yanrantí àti tí a n gbà fi ìró eni hàn yàtò sí àwon eranko.
Síwájúsi, èdè láti àgbáyé dé àgbáyé orìlé dé orìlé, ìpínlè dé ìpínlè, agbègbè dé agbègbè, awùjo dé awùjo oní èdè kan tàbí òmíràn tí won gbó, tí won sì ń só láàárín ara won èdè yàtò sí èdè bí eyà se yàtò sí eyà.
Orísìírísìí Èdè
(a) Èdè olóhùn àti
(b) Èdè tí kò lo ohun
(c) Èdè olóhùn ni àwon èdè tí o fí ohùn hàn nínú òrò, tí ó sì jé kí o ní ìtùmò nínú pípè yálà síso won. Ohùn méta ló wà nínú èdè Yorùbá:-
(i) Àmì Ohùn òkè /mi
(ii) Àmì ohùn ìsàlè \do
(iii) Àmì ohùn àárín – re.
(i) Òkè:- já, gé, jí, wá, ló àti béè béè lo.
(ii) Ìsàlè:- jà, kò, sùn, pòn, lò, à jà, àkò, àpòn àti béè béè lo.
(iii) Àárín:- lo, ko, pon, je, tata, aso, omo àti béè béè lo. Àwon èyà tí o ń so èdè tí a lèé ka kún èdè ni àwon wònyí. Yorùbá, Tiv, Urhobo, Efik, Itsekiri àti béè béè lo.
(2) Àwon èdè tí kò lo ohùn :- Àwon èdè tí kò ní ni pàtó ohùn tí a lè tóka sí gégé bí àmì ohùn tí ó gúnrégé wònyí:- Hausa, Calabar, Idoma àti béè béè lo.
ÈKÓ ÌMÒ ÈDÈ
Bí èdè tí wà gégé bí ònà ìfi èrò eni hàn. Tí ó sì jé òpómúléró náà ni a sì gbódò ko èdè kí a lè mo èyí tí ó ye fún kíkó àti kíko èrò eni sílè. Èkó nípa ìmò èdè yìí ni à ń pè ní ÈKÓ ÌMO ÈDÈ (LINGUISTICS)
ÈKA ÈKÓ ÌMÒ ÈDÈ
(i) Fónétíìkì:- Ni kíkó àti gbígbé ìró ohùn jáde yála láti inú gbogbo èya ara bi enu, imú àti béè béè lo. Ìlànà egbé IPA (International Phonetic Association) nípa kíko létà sílè ni a má a ń tèlé nígbà tí a bá fè se àdàko, fònétíìkì. Ìlànà yìí ni a fì máa ń ko ìró èdè fawélì tàbí kóńsónántì ti a gbó tàbí tí a kó sílè. kóńsónántì Ìyípadà Fawelì Ìyípadà
b B a a
D D e e
F F e є
G G i i
Gb gb o o
H h o o
J dz tàbí j u u
K k an ã
L l en є
M m in i
N n on õ
un u
P kp
R r
S s
S s
T t
W w
Y J
(ii) Fónójì:- ni ètò àmúlò ìró èdè kòòkan. Ìmò nípa ònà tí à ń gbà lo ìró èdè ni. Fónólójì ní ònà tí à ń gbà sín àwon ìró pò ni ònà tó jé pé yóò fí fún wa ní ìtumò. Àpeere. Ìró kónsónàntì ni ó máa ń sáájú tí ìró fawélì à tèlé e.
K + F
W + á = wá
Gbogbo ìró tó a bà pè jáde lénu ni a máa ń kosílè Àtubòtán gbogbo ìró tí à ń kò sílè ni pe: Fawélì méjì, méta tàbí mérin lè tèlé kónsónàntì kì í tèlé ara inú èdè Yorùbá. Bí àpeere: njé, ńkó, nnkan fonólójì, a ó se àkíyèsí pé àwon wònyí náà ń lo àwon àmì létà rópò.
Pèlúpèlú nínú ìmò- èdè (Lìngúísíìkì) àwon onímò èdè àgbáyé ni ìlànà tí won máa ń gbà ko àwon ìró álífábéètì kí ó lè baà rí bákan náà kárí ayé. Orúkò egbé yìí ni IPA (International Phonetic Association).
Ìlànà Àkotó: a e e i o o u an in on un en
Ìlànà I. P. A. /a/ /a/ /e/ /e/ /i/ /o/ /u/ /ã/ /i/ /o/ /u/ /є/
Bí a se ko ìró fawélì èdè Yorùbá Ìlànà Àkotó: b d f g gb i j k l m N p
Ìlànà I. P. A. /b/ /d/ /f/ /g/ /gb/ /h/ /dz/ /k/ /l/ /m/ /n/ kp
r s s t w y /r/ /s/ /s/ /t/ /w/ /j/
Níparí, A kì í se àmúlò ìró kóńsònántì ní òpin òrò Yorùbá. Bí àpeere
- bak * ajar * Oyeh
bá, ajá, Oyè
(iii) Mofólójì :- nì kíkó bí a sé le sà pe mofólójì fárape mófíímù. Mofíímu ni ègé tàbí fónrán tí ó kéré jù lo tí ó sì máa ń ìtumò nínú gírámà èdè Yorùbá. Inú àtúngé béè yóò so ìtumò re nù: A lè pín mófíímù nínú èdè Yorùbá sí ònà méjì pàtàkì. Awon náà ni
(i) Mófíìmù àfarahe.
(ii) Mófíìmù àdádúró.
Mófíímù àfarahe:- ni mófíímù tí kò le dá dúró gégé bí òrò kan fúnra re láì jé pé a kan òrò pò.
Mófíìmù àdádúró:- jé mofíímù tí o le dá dúró nínú òrò, ó dá ìtumò kíkún ni láìjé pé a tún se àfikún tàbí àtúnse kankan lára iní fónroún tàbí ègé béè. Mófíímù ni orísìírísìí òrò nínú gbólóhùn.
(iv) Síńtáásì:- Ni kíkó ìlànà bi ìró se n so pò nínú gbólóhùn, tàbí òhun ni ìlànà sí so òrò pò bèrè àti àpólà. Tí kòbá si òfin síńtáá sì ni, a ó ni ìpìnlè tó dúró sàn èyí tí a lè se àwárí itùmò láti inú àwon òrò tí asòpò papò. Bí àpeere: “Jùmòké lo sí oko” òrò orúko ni “Júmòké”
òrò ìse ni “lo”
òrò Atókùn ni “sí”
òrò orúkò ni “oko”
(v) Sèmántíìkì:- Ni kíkó nípa síso òrò lórí èko ìmò èdè jé. Tí o mú àmì, kókó àti títò ní sísè n tèlé láti mú itùmò tó péye wá.
ÀBUDÁ ÈKÓ ÈKA ÌMÒ ÈDÈ
(1) Ohùn tí a bá pè ní èdè gbodò jé ohùn tí a fí ìró èdè gbé jáde. Ìró yìí ni a lee pè ní ariwo tí a fi enu pa. a ó se e àkíyèsí èyí yàto sí pípòòyì ijó olónbòn n boùn dídún tàbí fífò.
(2) Èdè tún nílò nípa kíko o ìgbà pípè díè, kí ènìyàn tó le soo. Ó ti di bárakú tàbí àsà fún wa pé ìwádìí yìí ni àwon eléde gèésì ń kà sí nígbà tí àwon ba so pá “language is culturally transmitted” Omo tí a bá sesè bí tí a kókó ni èdè àti àwùjo jé kòríkòsùn.
(3) Gbogbo èdè kòòkan ló ní àwon ìró èdè tirè tí à ń pe ní fóníìmù (Phonemes). Fóníìmù yìí súnmó tí àwon eranko sùgbón ó sì tún rò ju ti eranko lo. Ó yàtò làti èdè kan sí òmíràn. Bí a bá mu fóníìmú yìí ló ni okòòkan. Kìí da itùmò ní kó wúlò ìgbà tí a bá kàn án pò mó fóníìmù mìíràn gan-an ló máa sísé. Bí àpeere ìró èdè /a/ /b/ /d/ /e/ /e/ kò dá ìtumò ni, àfí tí abá kàn wón papò bi obè, baba, adé àti béè béè lo. Iréfé àkíyèsí àti ìwádìí yí ni àwon onímò edà-èdè ń pe géèsí rè ní “Duality” tàbí “Double Articulation”. Ìwádìí pé àwon eye àti eranko tí won ní ìró èdè kò pò, iye èdè tí okòòkan ní kò pò pèlú. Bi àpeere :- Adìe ní ìró èdè bí ogún, ti Màlùú jé méwàá sùgbón kòlòkòlò ní Ogbòn.
(4) Èdè jé ohùn ètò tí a máa ń lò làti se àròjinlè àtí àrògún ní àwùjo.
ÌWÚLÒ ÈDÈ YORÙBÁ (1) Èdè wúlò pàtàkì jù lo fún kí a lè bà gbó ara wayé, so òrò léyìn tí ó máa ń fa àsoyé, àgbóyé àti àjosepò
(2) Èdè la fìn ko tàbí so ìtàn orísìírísìí ìbáà jé omodé tàbí àgbà.
(3) A tún máa ń fi èdè fa ewà yo nínú òpòlopò akéwì tí ó bá máà ń lo èdè Yorùbá, ti a ó sì gbédìí fún ewà akéwì náà. A lee sòrò pé “Ajá” èyí tóka sí eranko elésè mérin tàbí òrò “okùnrin” èyí tóka sí ènìyàn abèèmí elésè méjì.
(4) A máa ń lo èdè láti fi pàse fún enìyàn yálà láti fi kíni. Fún àpeere E kú aro, o Ekú òsán o àti béè béè lo.
ÌTÓKA SÍ (REFERENCE)
Olú Owólabí - Ìwé ìgbáradì ilé-èkó sékóndírì Àgbà
Báyò Adérántí Táíwò Olúnládé àti Afolábí Olábímtán