Ètò ẹ̀kọ́
From Wikipedia
Oluwatola, Oluwasola Gabriel
OLUWATOLA OLUWASOLA GABRIEL
ÈTÒ-ÈKÒ
Ètò-èkó se pàtàkì, béènì ó se kókó ni orìle-èdè Nàìjíríà, nítorí ó jé ònà pàtàkì tí àwon ènìyàn tè fi bá orílé-èdè míràn se òwò papò, pàápàá jùlo ètò-èkó ń fá ìgbéga fún ènìyàn nípa kíkó nípa orìsirísì nípa èkó bíì ìmò nípa èdá-aráyé, nípa ìmò eranko, nípa ohun ògbìn àti béèbéè lo. Bákan náà ètò. Èkó se pàtàkì jùlo ni èyà Yorùbá nítorí bí a bá wo orílè-èdè Nàijíríuà lápapò a ó ri pé èya Yorùbá ni ó mú ètò èkó ní òkúnkún dùn jùlo nítorí wón mo ìlò tí ó wà nínú ètò èkó ní àwùjo ti a ba wo orile-èdè nàìjíríà lápapò a maa ri pe èyà Yorùbá ni ó ka ìwé jù nínú èyà méta tí ó wà ní orílè-èdè Nàìjíríà. Sùgbón bí eto èkó se se pàtàkì tó yìí ó je nkan tí won ń fi owó yepere mú, nítorí àwon akékò kànkan won kò mo ìwúlò èkó náà. Bákan náà àwon ìjoba ni wón fa owó ètò èkó séyìn nítorí àwon ìgbésè tí won ń gbé lórí àwon olùkó ilé-ìwé wa kákàkiri ilè Nàìjíríà. Nítorí àwon olùko ye ní eni tí àwon Ìjoba máa fi gbogbo ònà gbé láruge. Nítorí ònà tí Ìjoba ń fi ìyà je àwon olùkó ni orílè-èdè Nàìjíríà tún bò ń mú ìfà séyìn bá ètò-èkó nípa pípé san owó àwon olùkó àti àìsètò Ibùgbé fún won, nítorí àwon ni ó ye ní eni àkókó ní orílè èdè. Bí ó tilè jé wí pé won kò ní iyì. Nítorí àwon kì wón jé ìpìnlè sè gbogbo àwon Ògálóògá ní enu isé àti àwon olórí orílè-èdè gbogbo. Nítorí ìdí èyí ti ìjoba ń gùn lé yìí ó mú àdínkù bá ètò-èkó ní orílè-èdè Nàìjíríà lápapò. Ní ònà míìràn èwè Ìjoba tún mú àdínkù bá ètò-èkó nípa gbígbe ètò ìlànà èkó èdè Nàìjíríà kúrù ní bí ó se wà láti orí oókan sí méfà sí méta sí méta lo sí orí oókan sí mésan, mesan si méta. Ìdí tí mo fin í àdínkù nip é, ní ayé òde òní a rip é àwon omo tí won ń bí báyìí máa ń ní Ìdàgbà sókè kíakía pàápàá jùlo àwon omo Obìnrin wa, Ìdí tí mo fi mú enu ba àwon obìnrin ní pé, àwon Yorùbá bò wón ní Obìnrin ń gún oún ó ń yò sèsè kò mò pé ohun tí yóò lé òun kúrò ní ilé bàbá òun ni. Ìdí tí mo fi pa òwe yìí nip é, omo bìrin tí ó bèère sí ni gún omú láti ilé-ìwé kárùn kí ó tó jáde ilé-ìwé mesan tí omú àyà rè tí pòju bí ó ti ye lo èyí lè mú àdínkù bá ètò-èkó omo náà. Èyí tí ó lè fa ìdáwórúró fún irú omo náà nítorí ìtìjú bí ó se yàtò sí àwon egbé rè. Bákan náà ni ó rí fún omokùnrin nítorí ìdí èyí ìyípadà tí ó bá ètò èkó yìí lè fá, kí ètò-èkó máà ní ìdàgbà sókè ní orílè-èdè Nàìjíríà.