Ìgbàgbọ́
From Wikipedia
ÒGÚNRÁNTÍ DAVID BABÁJÍDÉ
FAITH, HISTORY AND INTEREST IN THE WORD OF GOD
ÌGBÀGBÓ, ÀWON ÌTÀN ÀTIJÓ ÀTI ÌFÉ NÍNÚ ÈKÓ NÍPA OLÓRUN
A ó ri i pé “Ìgbàgbó” máa ń wá nípa ìmò. Ìmò leè wá ní orísirisI ònà; nípa èsìn ààsnà ti ilé àti ìlú ati èrò òbí, ìjo; egbé àti béè. Èyàn tó bá sì jogún ìtàn ayé àtijó nípa bóyá èèkó ní ìmò yíì si. Èyàn le ní èkó nipa ohun kan, léhìn èyí, ìmò. Fún àpeere, èkó nipa Olórun mú ìmò wáá. ìmò nípa rè lákókó ati ohun yókù. Kí ni èyàn fé gbàgbó bí kò bá ní ìmo rè. ohun eyé je leje ń gbéfò. Ìgbàgbó lemú kí èyàn se ohun. Ìmò ni o n fún ni ìgbàgbó yìí. Èkó ni ó sì ń jé kí èyàn jí sí ìmò yí bóyá bíi esìn tí ó le fún ni ní èkó nipa Olórùn. Èkó kékeré àkókó yíò kanlèkùn okán sí ìgbàgbó. Bí èyàn bá síì okàn sí ti Olórun, á gbàgbó yíó sì tèsíwájú. Èkó ìsènbáyé ati ìtàn le jé kí èyàn ji si ìmò náà. Ìmò àkókó sí nipa Olórun yí mú àyípadà dé bá omo éníyàn yó sì fé, léhìn èyí, láti mo èkó nípa ohun tuntun tí ó dé bá ayé rè. Èyí á fun ní ìgbàgbó sí nípa onírurú ohun ti Elédùmarè da àti ohun tí ó le mu dá. Gégé bí ìtan ayé àtijó, orísirísI ònà ni Eledumarè gbà pàdé àwon bàbá wa tí ó jé pé ati ní àkoólè ní orísirísi èsin. àkoólè ní pa nkan ní ó ń fún ní ní ìmò nípa rè. Àkoólè Olórun àti nípa Olórun fún ní ní ímó nípa ti Olórun. Àwon àkoólè yí mú ímó àkókó wá. Bí àwon baba wa se gba àwon àkoólè yí tí wón sì ń gbàgbó ni wón ń ti lé ìrandéran lówó. Ìmò yí ń mú ìgbàgbó wá. Ìgbàgbó àkókó ń mú ìfé nínú èkó àti ìmò nípa Olórun síwájú si wá. Ìfé nínú èkó nípa Olórun sì mú kí ìgbàgbó ènìyàn nínú Olórun pò si. Bí ènìyàn bá sì ní ìgbàgbó, tí kò sì se iyè méjì, ohun rè á máa ja so déédé. Igbàgbó le fún lágbára láti se ohun kan. Ó le jé kí ènìyàn ní èrò, ìse àti ìrísí òtò. Bí Olórun se ń bá àwon baba wa kòòkan pàdé ní ìgba nì, Ó ń bá ènìyàn pàdé ní òní nípa èrò àti èrò sí ìgbàgbó. Nínu èrò yí, ènìyàn ní agbára láti Yàn fún Olórun ní àkóko kan àti ní ìgbà dé ìgbà. Níwájú si èrò yí á jé kí ènìyàn bá ara rè pàdá. Ó sì le ma ara rè ní èmí okàn àti ara.