Ẹ̀kọ́ nípa ẹ̀dá
From Wikipedia
Eko nipa Eda
Contents |
[edit] Ewébè
Gbúre, ilá, tètè, sokoyòkòtò, yánrín, òdú, ìsápá, ìgbó, ìgbágbá, ewúro, oóyó (ewéédú)
[edit] Awon aràn
1. Sòbìà 2. Eépà 3. Áràn mùjèmùjè/Aràn Okèelè 4. Jèdíjèdí 5. Ejò inú 6. Tanmona 7. Ekóló
[edit] Orísìírísìí ilè
Yanrìn ,
Amò,
Ìlèdú,
Taràá.
[edit] Àwon Eye
1. Ògòngò 2. Pépéye 3. Adie 4. Àsá 5. Àwòdì 6. Odíderé 7. Igún/Igúnnugún 8. Eyelé 9. Tòlótòló 10. Òwìwí 11. Òkín 12. Ológosé 13. Eye Oba 14. Lékèélékèé 15. Wasowaso 16. Àdàbà 17. Tin-ín tin-ín 18. Èluulùú 19. Àparò 20. Ègà
[edit] Àwo n Òdòdó díè
1.Korotin 2.Àkálífà 3.Ìlá abilà 4.Alámáńdà 5.Kerebùjé 6.Marigó 7.Píńróòsì 8.Róòsì 9Abóòrunyí 10.Bó-giri-rìn 11.Òdòdó 12.Okán 13Yún-únyun 14.Ìgbàlódó/Ìràwò ilè 15.Ìdò 16.Oró agogo/oró adétè
[edit] Àwon Igi
Afàrà, Ahùn, Idí, Gedú, Ìrókò, Ògánwó, Òmò, Òsè, Apá,
[edit] Àwon Èso
Òpòn Òyìnbó/Ekíkún, Àgbàdo/Oká, Ògèdè wéwé, Ìbépe, Osàn banbó, Tòmátì, Máńgòrò, Èpà, Kajú, Èpà, Èwà/Erèé, Ilá, Ìgba, Obì, Òronbó weere, Òronbó ńlá, Gúáfà, Kerebúùtù, Ìyeeyè, Òro, Orógbó, Àgbálùmò,
[edit] Orísìí Eranko
1. Ésin 2. Mààlúù 3. Ràkúnmí 4. Ìnàkí 5. Akítí/Ìjímèrè 6. Efòn 7. Èsùró 8. Elédè 9. Ajá 10. Ewúré 11. Erin 12. Ehoro 13. Ológbò/Ológìnní 14. Eku 15. Emó Òyinbó 16. Òkéré/Ase 17. Òkété/Ewú 18. Òyá/Òkúrú 19. Alégbà/Awòn 20. Alákedun/Aáyá 21. Àdán 22. Ògà/Alágemo 23. Òòrè
[edit] ÀWON ERANKO TÍ Ó LÈ GBÉ INÚ OMI
1. Eja 2. Òkásá 3. Òkàsà 4. Ìsáwùrú 5. Eja oníràwò 6. Òní 7. Erinmi 8. Tanwíjí 9. Káwóbojú 10. Akèré 11. Ópòló 12. Ákàn 13. Awòn Ahónríhán/Alángbá 14. Jomijòkè 15. Ìròmi 16. Jomijòkè
[edit] ERANKO AFÀYÀFÀ
1. Afàyàfà 2. Ejò 3. Ejò olóró 4. Ikarahun 5. Igbín/Èsàn 6. Òkùn màkà 7. Tasutasu, òkùn 8. Ekòlò 9. Alàngbá/Aláàmù 10. Ìjàpá/Áhun 11. Àlégbà/Awón 12. Mònímòní; Aárà; 13. Nini; Ìgòngò
[edit] ÀWON ERANKO TÍ Ó Ń JE EWÉ
1. Mààlúù 2. Esin 3. Ewúré 4. Èsùró 5. Ehoro 6. Emó oyìnbo
[edit] ÀWON KÒKÒRÒ
1. Èfon 2. Esinsin 3. Ìdun 4. Irù tàbí Asarun 5. Eégbon 6. Lámilámi 7. Agbón 8. Aáyán 9. Tata 10. Ìrè 11. Òbànùnbanùn 12. Esú 13. Oyin 14. Àfòpiná 15. Labalábá 16. Èèrà 17. Ìjálo/èèrùn 18. Ikán 19. Kaninkanin 20. Emírín 21. Kòtónnken 22. Àkekèé; Atansánko 23. Àntaakùn 24. Jìgá 25. Eégbon
[edit] ÀRÙN TÍ KÒKÒRÒ Ń FÀ
1. Onígba méji 2. Ìgbóná/Ibà 3. Ára sísú; Èyí; ègbèsi 4. Èyín 5. Ooju 6. Ìbésè/kányàán 7. Èjè dúdú 8. Ìgbé òrin/igbékínkín