Ẹ̀kọ́ nípa kòkòrò
From Wikipedia
Awon Kokoro
[edit] ÀWON KÒKÒRÒ
Orisirisi kokoro lo wa ni ile ede yoruba, die lara won ni yi: 1. Èfon
2. Esinsin
3. Ìdun
4. Irù tàbí Asarun
5. Eégbon
6. Lámilámi
7. Agbón
8. Aáyán
9. Tata
10. Ìrè
11. Òbànùnbanùn
12. Esú
13. Oyin
14. Àfòpiná
15. Labalábá
16. Èèrà
17. Ìjálo/èèrùn
18. Ikán
19. Kaninkanin
20. Emírín
21. Kòtónnken
22. Àkekèé; Atansánko
23. Àntaakùn
24. Jìgá
25. Eégbon
26. Tambolo