Bólá Ìgè
From Wikipedia
Bola Ige (1930 - 2001) je oloselu omo orile ede Naijiria lati eya Yoruba ni apa iwo oorun ile Naijiria. A bi ni ojo ketala osu kesan odun 1930, o di ologbe ni ojo ketalelogun osu kejila odun 2001.
A bí ní ìlú Esa-Oke ni ìpínlẹ̀ Osun. Ìgè jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo lati osù kẹwàá ọdún 1979 títí dé osù kẹwàá ọdún 1983. Lẹ́yìn ìgbàtí ìjọ̀ba olósèlú padà dé ní ọdún 1999 Ìgè di Alákòóso ìjọba àpapọ̀ fún ìdájọ́ àti Agbẹjọ́rò ìjọba àpapọ̀.