Chinua Achebe
From Wikipedia
Chinua Achebe (ojoibi November 16 1930) jẹ́ ọmọ orile ede Naijiria lati eya Igbo ni apa ila oorun Naijiria. Ojogbon ninu imo ikowe (literature) ni Achebe je, opo ni ile Afrika ni won si mo Achebe gege bi okan ninu awon omowe (intellectual) pataki ti a jade ni ile Afrika. Iwe re Igbesiaye Okonkwo (Things fall apart) ni o je eyi ti o gbajumo julo ni ile Afrika leyi igba ti a ti seyipada re si ogun logo ede ka kiri aye.