Ipin-tokasi:Imo Sayensi
From Wikipedia
Imo Sayensi
Imo Sayensi je apapo Imo Oniriri ti o se f'idi mule, awon Omowe kakiri ile-aye, ati awon ona igbajopo ti a le fi se iwadi Agbala-Aye ti a mo gege bi Ona Imo Sayensi. Imo Sayensi Idaba n se ayewo Idaba; Imo Sayensi Oniawujo n se ayewo Eda Omo Eniyan ati Awujo.
Ipin-Itokasi:Imo Sayensi