Web Analytics

See also ebooksgratis.com: no banners, no cookies, totally FREE.

CLASSICISTRANIERI HOME PAGE - YOUTUBE CHANNEL
Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions
Informatics - Wikipedia

Informatics

From Wikipedia

Informatics (Ifitonileti)

OWOLABANI JAMES AHISU ati AKINDIPE OLUWABUNMI TOPE

Ètò Gírámà

Ìfáàrà

“Ní àtètèkóse ni òrò wà …” (Jóònù 1:1)

Kì í se ohun tó dájú ni pé akékòó èdè kòòkan yóò jiyàn pé òrò ni wúnrèn ìpìlè fún ìtúpalè nínú àwon gírámà. A lè yígbà yígbà kí a wádìí lítítésò fún àríyànjiyàn lórí mófíìmù, sùgbón léyìn gbogbo atótónu yìí, kí ni a rí? Sé ó léni tó n so mófíìmù tó dáwà tí won kìí sìí se òrò fúnra won? kí ni ó wà nínú òrò–síso tó ní ìtumò? Kí ni àwon ìdánudúró fún gbólóhùn? Òrò ni àárín, inú, àti àwon ìbèrè òrò.àjòmó ìbèrè, kódà fóníìmù pèlú kò lè dá dúró tí kò bá ti lè làdì sí ìtumò nínú òrò. Ní àtètèkóse ni òrò wà. Ó wà níbè láti dá ayé ofò sílè, láti mo àti láti tún òrò–síso mo, láti fikún, láti yo kúrò àti láti mú ye ní orísìírísi ònà.

E jé kí á padà kúrò ní àníjé ìmó wa lo sí ajúwè nínú gírámà; ètò rè ìlànà ìfojú- ààtò-wò àti àlàyé rè. Fífi ojú gbogbo ayé wo gírámà, a máa se àpèjúwe ètò gírámà pèlú àwon òrò, ní ìbèrè, ní pàtàkì pèlú èdè Gèésì àti Yorùbá kí a sì fi àpéjo àwon ènìyàn tí n gbó òrò sílè láti dásí ìfihàn nípa títeríba fún èrò ìlànà tí a fi lélè fún ìtúpalè ní èdè tirè, èdè ènìyàn mìíran. Àkíyèsí ni pé tí èdè Gèésì àti Yorùbá, àwon èdè tí kò tàn móra won tó gbilè, ni a lè tún se àtúnse rè sí àwon òfin tí a ti gbìmò won níbí, ó se é se kí àwon nnkan tí à n rò jé òtító, kí ó sì sisé fún èdè mìíràn títí dé àwon àbùdá àìròtélè àwon èdè kan. Bí èfè yen kò bá mú ìbàjé wá, à á se àtúnwí àbá kan náà pèlú èyí: àwon tí won kò gba èyí gbódò mò nínú won pé nígbà tí wón bá n se ìtúpalè àwon èdè won ni àwon èrò yìí, èrò yìí ni a máa se atótónu wa tí ó kún lórí rè fún àpeere èdè Yorùbá, ‘Hausa’, èdè Gèésì, èdè ‘Ibibio’… àwon èdè tí a kójo pèlú ìyàtò ni wón ní ìbásepò kankan nítorí pé wón jé èdè ènìyàn. Síbèsíbè, tí a bá fi owó gírámà kan náà mú won, à n so pé wón ní ìjora, bí okùnrin elédè Gèésì se jo okùnrin elédè Yorùbá kan, tí ìyàtò won sì jé ti àwò won. Ìyókù orí yìí yóò mú wa wà ní ìmúra sílè láti rí ìdí tí àwon onímò èdè fi n kóòdù àwon ìtúpalè won bí wón bí wón se n se.

2.1 ORO Fífún àwon òrò wònyí lédè Gèésì:

1. Okùnrin, ìwé, kálámù, òòtè, ife, Olè, síbí, tábìlì, òsùká, téèpù,

eni tó rí so Gèésì kò ni ní wàhálà nípa sísèdá:

2. Àwon okùnrin , àwon ìwé, àwon kálámù, àwon òòtè,  àwon ife, Àwon síbí, àwon tábìlì, àwon òsùká, àwon téèpù.

Ó ti pinu ní okàn rè láti mo ìsodorúko àwon òrò náà àti àwon òrò orúko (Latin: nomen ‘name’) ni a lè so di òpò ----- àwon àpeere pò nípa àwon nnkan ti a so lórúko. Nípa ti iye ìtèsí rè, a lè fi àwon òrò mìíràn bí i kan tàbí náà kún òkòòkan àwon òrò náà. Yíyéni láì sàlàyé tóbé è jùbé è lo gírámà rè ni gbìmò tíórì kan pé kí gbogbo àwon òrò orúko gba àwon átíkù kan tàbí náà. Lára àwon ìdájó rè ni ó jé pé átíkù wo ni ó síwájú tí ó sì tèlé àwon òrò pàtàkì nínú ìwé tí à n kà lówó láti túmò rè, sùgbón kò sí ohun tí ó dá yàtò nípa:

3. ife náà ~ ife kan

síbí náà ~ síbí kan

Ohùn kan tó tún dìjú ni pé, nígbà tí a bá mú ìkan lára àwon átíkù wònyí, ní dandan òkan lára àwon tó lè dá dúró tí a pín sí abé òrò orúko gbódò tèle, sùgbón kì í se dandan kí síso òrò jé òotó! Ohunkóhun tó bá selè, à n tè síwájú láti so pé bí a bá ní òrò kan, ohun mìíràn, tí ó wá láti ìpín mìíràn, lè tèle tàbí kí ó máa tèle, nínú síntáàsì, a máa n lo ònà mìíràn làti so pé:

4. X: Y; + {__ (Z)}

Òrò kan tó jé X ni a pín gégé bí Y àti pé ó lè jeyo pèlú àwon òrò Z, Z jé òrò kan tí ó lè wà tàbí kí ó má wà nílé nígbà náà. Tí a bá n fojú isé onà wò ó òrò kan tó jé X ni ìpín onítumò àdámò (ìsòrí òrò) Y ní abgègbè tó saajú òròmìíràn Z, wíwá níbè Z jé wòfún. Àkosílè afòyemò tí òkè yìí ni à n pè ní àpíntúnpín sí ìsòrí tó múná dóko ni a jíròrò lè lórí nínú Yusuf (1997). Tí a bá padà sí àwon àpeere (1,2) ti òkè, eni tí n sòrò lórí bí a se lè mo àwon tí ó dá dúró yìí to jé òrò oruko tí o lè wà ní ipò tó se kóko; olùwà àti àbò. Lára àwon ìmò rè nípa àwon òrò wònyí ni pé a lè fún wón ni àwon ipa kan láti kó; tí a bá ní ká wò ó kí ni ìwúlò won tí won kò bá kó ipa kankan ní àyíká gbólóhùn tàbí ofò won. Fún àpeere, olè kan jé òsèré, olùkópa tí ó bá kópa níhìnìn tàbí òhún láti mú àpíyadà wá. Nígbà tí ó bá n serè, a mò pé ó lè jalè. Kódà kì í se olè tí a kò bá mò ó sí eni tó jí nnkan kan nítorí nínú gbólóhùn bí i.

5. Olè náà jí kálámù

Òrò náà tó jé ‘ole’ so ohun tó pò. Ó jé òrò tó mú náà, tóje átíkù, ó lè yàtò fún oye àwon olè àti pé ó je ÒSÈRÉ nínú àyè ofò tó lè mú ìyípadà bá ìfarasin kálámù náà. Rántí pé òrò náà ‘kálámù’ wà ní ìsòrí yìí náà pèlú; ó máa gba átíkù náà/kan tí a lè gbékalè ní òpò (àwon kálámù) àti pé a fé fà á yo, gégé bí àwon ojúgbà rè, wí pé ó jé olùkópa ní àyíká gbólóhùn náà sùgbón ní báyìí ó n kó ipa ohun tí wón jí, ipa náà ni a máa pè ni ÀKÓSO. Opolo wa so fún wa pé kálámù kan lè jé ohun ÈLÒ fún ìbánisòrò. Àwon ipa náà, tí àwon álífábétì nlá dúró fún ni à n pè ní Àwon ipa asekókó, a lè gé e kúrú sí ‘Theta – roles’, tí wón máa n kò gégé bí i ‘Ø roles’, bí ìtèsíwájú bá se n bá ìtúpale wa. Ko lè sí ohun ìtókasí tó dúró, àwon olùkópa kan tí a lè tòka sí, nawó sí, dárúko, sòrò nípa, tí kò ní gba ‘Ø role’ kan. Àwon àjoni tí a sábà náa n rí ‘Ø roles’ je OLÙSE, OLÙFARAGBA, (nígbà mìíràn tí a máà n pè ni Àkóso), ÒPIN àti ÈLÒ. Òpòlopò àwon onímò lìngúísíìkì mo àwon mìíràn dájú.

Àwon àbùbá àdámó òrò wà tí a lè tóka sí báyìí. Àwon àbùdá mìíràn máa hàn kedere tí a bá gbé èdè tó yàtò sí èyí tí a ti mò télè yèwò. Nítòótó, a máa so pé ìwúlò wò ni ó wà nínú kí a máa sòrò nípa àwon ohun tí a kò rí nínú èdè wa! Ìkìlò: À n sòrò nípa àwon àbùdá tó wà nínú èdè ènìyàn, kì í kan n se nínú èdè Gèésì tàbí èdè Yorùbá. Rántí ohun tí a rò nípa Gírámà Àgbáyé, Èdè Gèésì, èdè Ìgbò, èdè ‘Eskimo’, èdè ‘Japan’…….. jé díè lará èdè ènìyàn tí wón sì ní àwon ìyàtò won, nínú ohun tó se kókó báyìí, fífún àwon òrò asèdá òrò asèdá bí i ÒPÒ ‘Ø role’, àwon ipò onítumò gírámà, abbl.

E jé kí á fi àbùdá kan kún àwon àpeere wa. Àwon òrò náà ni a lè yí padà. Ní béè à á ní:

6a. Okùnrin alágbára kan

b. Ògbójú olè kan

d. Igi oaku kan

e. Téèpù mímógaara kan

e. Ife kan tó kún fún kofí 

f. Òsùká kan fún ìbòsè aré bóòlù àfesègbá

Àwon wònyí jé àwon èpón tó jè wí pé bí a bá yo wón kúrò ìtumò àwon òrò náa kò ní dínkù (ìsomó). Àwon àkámó tí a lò nínú àpíntínpín sí ìsòrí tó múná dóko àti àwon tí a fihàn ní orí kìíní, ni a lè lò báyìí, bí i (T).

7a. ife kan ([tó kún] fún kofí)

b. téèpù (mímógaara) kan

c. Okùnrin (alágbára) kan.

Àwon ohun tí a fi sínú àkámó ni à n pè ní àwon ìsomó, won kò ní apíntúnpín sí ìsòrí, won kì í se dandan, wón je èpón –on wòfún. Nígbà tí àwon wònyí tún wúlò níbò mìíràn, a fe yán an pé kìí se gbogbo àwon èpón ló jé wòfún. Kódà nígbà tí won kò bá ní ìtumò àdámò wón wúlò. Fún àpeere, oba tàbí olorì kò níyì bí oba tí won kò bá ní ìjoba tiwon. ní béè a ní:

8a. Oba tí Èkó

b.  òbí ti Agbor

d. Oba àwon Júù

Kódà Oba bìnrin ‘Elibabeth’ tí ó tó láti se ìtóka ni a mò pé ó ní agbára lórí ilè Gèésì. Àkíyèsí pé láti so pé Oba bìnrin náà, láà jé pé ènìyàn n gbé nílè Gèésì tàbí tí iyè rè so pèlú oríle – èdè náà, máà sàì nítumò. Orúko àbíso lè tó láti mo àwon orí oyè, sùgbón ìjoba won tí se pàtàkì jù, èpón wòfun. Àwon èpón ni à n pè ní Àwon Àfikún. Ní kúkúrú, àwon èpón PP ti oba àti oba àti oba je wúnrèn tí a ní lò.

2.2 Àkópò kúkúrú kan

Àwon òrò, tí a fihàn gégé bí i àwon òrò orúko, gba àwon nnkan mìíràn móra dandan, ‘DET’, Àwon ipa asekókó, ÌSODÒPÒ, àwon kan– npá àti wòfún (ákámó), àwon Àfikún àti àwon Ìsomó bákan náà, àti àwon mìíràn tí a kò ménu bà. Àwon àbùdá àdámò ti olùso èdè rè gbódò mò ni àwon wònyí. Ó jé dandan pé ó mo òpòlopò, lára èyí tí a máa so tó bá yá ní ìfìwàwèdá. A fé je kí àwon akékòó mò pé àwon nnkan wònyí jé àìkó, lára àwon akówòó rìn UG nínú àká – òrò náà (atúmò èdè tí iyè náà). A ménu bà á pé àwon nnkan wònyí kìí hànde bákan náà, sùgbón ó lè gbón fara sin sínú àwon kóòdù mofólójì nínú òrò náà, ní àwon àyíká tí a kò funra sí.

2.3 Òrò náà (2)

Àwon àkójopò àwon òrò tó yàtò sí ti àkókó máa fún wa ni àwon nnkan. E je kí a mu àwon òrò tó n so nípa àwon òrò orúko.

1. talk, kill, endure, wait, eat, drink, write, see

fún àwon elédè Gèésì, àwon òrò wònyí jé òrò ìse (Latin: verbum ‘Word’), won le fi àsìkò ìsèlè hàn nípa gbígba àwon àfòmó:

2. talk: talks, talked, talking,  

kill: kills, killed, killing.

X X-s X-ed X-ing.

Àwon gégé bí àwon òrò orúko lè gba àwon àbò àwon kan wòfún ni (àwon òrò ise agbàbò) nígbà mìíràn ó jé wòfún nígbà tí wón bá jé aláìgbàbò sùgbón tí won bá gbà àwon àbò tan, tàbí kí won máà gba àwon ìsomó kankan.

3. eat (NP)

kill (NP)

drink (NP)

[+ liquid].

Àwon ìsomó máa n borí àwon àpólà (tí ó lè je eyo òrò kan soso) sí àwon àpólà orúkò. Níbí ni a se àpèjúwe ránpé nípa àwon Àfikún òrò ìse sí.

4a: eat ([NP an unripe mango])

b. destroy [NP the termitarium]

c. said [s. that [s the NBA examination is

canceled]]

d. put [x [NP salt] [pp in the soap]]

e. saw [NP Móremí].

Àwon òrò ìse aláìgbàbò ni a máa fihàn nísàlè, pélù àwon ìsomó.

5a Jòkó sórí ení

b. Sùn síjòkó èyìn òkò

d. La àlá

e. Kú.

Nígbà tí àwon yìí kò gba àwon àfikún, wón lè, nípa ìgba àkànse gba àwon àbò - àwon àbò àkànse tí a so mo won tàbí tí a sèdá láti ara won. Wón fejó Èsù so nínú Bíbélì pé ó n gba Éfà níyànjú láti ma bèrù nípa jíje èso èèwò, tó wí pé, “Èyin kò ní kú kan”. Èsù kò nílò àti yí òrò ìse aláìgbàbò sí agbàbò

Nitóri pé wón n sòrò nípa àwon òrò orúko wón fi àwon nnkan pamó lórí àwon irú òrò orúko (kódà yíyípadà) ní àwon èdè kan. Èdè Gèésì kìí se àpeere tó dára nípa bí òrò ìse se lè yí òrò roúko tí a bá wèyìn, ipa asekókó ÒSÈRÉ, ÀKÓSO, ÈLÒ, abbl wá tààrà tàbí àìsetààrà láti ara òrò ìse. Fún àpeere alè máà ri sùgbón a mò pé N kan náà (nítòótó NP) ni ó n kú nínú:

6. Olú pa olè náà

Olè náà ni olú pa Àti pé kò sí àníàní, NP kan náà tó fa ikú bó tilè jé pé ìtò gégé ní àwon olùkópa nínú gbólóhùn méjèèjì wà. Fún béè Olú ni ÒSÈRÉ nínú gbólóhùn méjèèjì nígbà tí Olè náà jé Àkóso nínú méjèèjì bákan náà. A lè sòrò nípa àwon òwó òrò mìíràn, tó yàtò sí Àwon òrò orúko àti àwon òrò ìse, sùgbón e jé kí á padá séyìn láti wo àwon ìjíròrò wa fún ìbáramu. À n so pé òrò kòòkan, bó jé òrò orúko tàbí òrò ìse, máa n wá pèlú àwon nnkan. Nínú ìbásepò won, àwon òrò náà n sisé lórí ara won to fi jé pé àwon òwò kan a gbà àwon mìíràn yóò sì fún won ní àwon àbùdá kan. Òrò orúko náà, tó máa n jé olùkópa, kìí se ÒSÈRÉ tàbí ÀKÓSO tí òrò kò bá fún won ní irú ipa béè. Nínú òrò – èdè tí ayé (tí a gbé wonú gírámà) òrò ìse tó n darí àbò APOR rè fún ìdí èyí, ó n fún ní isé (ní báyìí, Ø role nìkan, àmó ó lè se àyànse àwon àwòmó mìíràn).

Gégé bí olùso èdè se nu ìmò nípa àwon nnkan wònyí láìkó tí ó sì je pé dandan ni ó n tèlé àwon ofin yìí, se a kò lè so pé àwon ogbón ètò yìí jé abínibí gégé bí mímí se je?

2.4 Àwon ibi gíga  

Ìwòn mìíran nì a ti menu bà télè, nípa òrò náà, ohun náà ní pé kìí jeyo ní dídáwà. Olè di Olè náà, ògbójú Olè náà, ògbójú alágbára Olè náà pèlú ìwo, abbl. Àwon àlèpò òrò náà sí àwon òwó tí ó tóbi pèlú ìrànlówó àwon ohun tí a pè ní àwon àpólà. Nítorí pé àárín òrò, òrò gangan tí a bá túnse nì yóò dúró fún odidi àpólà, a máa n pé irú won ni Ori. Ni a se máa rí i, òrò orúko ní ó máa n jé orí fún Apólà orúko (APOR), òrò ìse fún Àpólà ìse (APIS), òrò àpèjúwe fún Àpólà àpèjúwe (APAJ)….,X tàbí Y tún àpólà X (XP) àti àpólà Y (YP) bákan náà. Léèkan sí, ká wò ó pé olùso èka –èdè rè mo púpò nípa rè. Yorùbá máa mò mò pé omo ‘child’ ni a lè tó àwon òrò èpón mó bi i omo kékeré ‘small child’, omo baba Ìbàdàn ‘the child of the man from Ìbàdàn’ tàbí omo náà “the child” kò di dandan, àti pé kódà, won kò tí ì kò ní àwon àtòpò yìí rí. Àti wí pé opolo tí olùso èka–èdè yìí n lo ni a fé gbéyèwò nínú gírámà, Akitiyan láti mo ohun tí ó mò láì kó. Se kò pani lérìn-ín, olùso èka – èdè, tàbí omodé kan n kó àwon orímò èdá–èdè kò ní ìtumò sùgbón òótó ni.

A se àfiikún àwon àpólà tí a kó tí olùso èka–èdè lè lò pé kò ní èkun ó sì peléke. Àwon iní ìhun béè lè kún fún àwon èròjà wòfún tí ó wonú ara won. Sùgbón èyí kéyií tó bá selè, àpólà gbódò ní orí, títèlé àwon ohun tí òfin níní orí gbà, tí a pè ní ‘endocentricity requiremrnt’. Nítorí béètí a bá ní òrò kan W, ó gbódò di W max tí a túpalè ní síntáàsì gégé bí i WP (for W-Phrase) tàbí W” (W- double prime (=bar)).

Static Wikipedia (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -

Static Wikipedia 2007 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -

Static Wikipedia 2006 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu

Static Wikipedia February 2008 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu