Web Analytics

See also ebooksgratis.com: no banners, no cookies, totally FREE.

CLASSICISTRANIERI HOME PAGE - YOUTUBE CHANNEL
Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions
Iselu - Wikipedia

Iselu

From Wikipedia

Iselu

Tella, Samson Adekunle

TELLA SAMSON ADEKUNLE

ÌSÈLÚ

Ní àwùjo Yorùbá, á ní àwon ònà ìsèlú tiwa tí ó dá wa yàtò sí èyà tàbí ìran mìíràn. Kí àwon Òyìnbó tó dé ní àwa Yorùbá ti ni ètò ìsèlú tiwa tí ó fesèmúlè. Tí ó sì wà láàárin òpò àwon ènìyàn. Yàtò sí tí àwon èyà bí i ti ìgbò tí ó jé wí pé àjorò ni won n fi ìjoba tiwon se (acephalous) tàbí ti Hausa níbi tí àse pípa wà lówó enìkan (centralization). Ètò òsèlú Yorùbá bèrè láti inú ilé. Eyi si fi ipá tí àwon òbí ń kò nínú ilé se ìpìlè ètò òsèlú wa. Yorùbá bò won ní, “ilé là á tí kó èsó ròdé”. Baba tí ó jé olórí ilé ni ó jé olùdarí àkókó nínú ètò ìsèlú wa. Gbogbo èkó tó ye fún omo láti inú ilé ni yóò ti bèrè sí kó won. Bí i àwon èkó omolúàbí. Tí èdèàiyèdè bá selè nínú ile, bàbá ni yóò kókó parí rè. tí kò bá rí i yanjú ni yóò tó gbé e lo sí òdò mógàjí agbo-ilé. Agbo-ilé ni ìdílé bíi mérin lo sókè tó wà papò ni ojú kan náà. Won kó ilé won papò ní ààrin kan náà. Tí mógàjí bá mò ón tì, ó di odo olóyè àdúgbò. Olóyè yìí ni ó wà lórí àdúgbò. Àdúgbò ni àwon agbo-ilé orísìírísìí tí ó wà papò ní ojúkan. A tún máa ń rí àwon Baálè ìletò pàápàá tí wón jé asojú fún oba ìlú ní agbègbè won. Àwon ni òpá ìsàkóso abúlé yìí wà ní owó won. Ejó tí won kò bá rí ojúùtú sí ni wón máa ń gbé lo sí odo oba ìlú. Oba ni ó lágbára ju nínú àkàsò ìsàkóso ilè Yorùbá. Àwon Yorùbá ka àwon Oba won sí òrìsa Ìdí nìyí tí won fí máa ń so pé: Igba Irúmolè ojùkòtúu Igba Irúmolè ojùkòsì Òkan tí ó lé nínú rè tí ó fi jé òkànlénú tàbí òkàn-lé-ní-rinwó (401), àwon oba ni. Won a ní.

KÁBÌYÈSÍ ALÁSE. ÈKEJÌ ÒRÌSÀ Oba yìí ní àwon ìjòyè tí won jo ń sèlú. Ejó tí oba bá dá ni òpin. Ààfin oba ni ilé ejó tó ga jù. Oba a máa dájó ikú. Oba si le è gbésè lé ìyàwó tàbí ohun ìní elòmíì. Wón a ní: Oba kì í mùjè Ìyì ni oba ń fi orí bíbé se. A rí àwon olóyè bí ìwàrèfà, ní òyó ni a ti ń pè wón ní Òyó-mèsì. Ìjòyè méfà tàbí méje ni won. Àwon ni afobaje. A rí àwon ìjòyè àdúgbò tàbí abúlé pàápàá tí ó máa ń bá oba se àpérò tàbí láti jábò ìlosíwájú agbègbè won fún un. A tún ń àwon èsó tí ó ń dáàbò bo oba àti ìlú. Àwon ni won ń kojú ogun. Àwon ni o n lo gba isakole fóba. A tún ní àwon onífá, Babaláwo àti béè béè lo. Ètò òsèlú wa tí ó fesè múlè yìí ni ó mú kí ó sòro fún àwon òyìnbó láti gàba tààrà lórí wa (Indirect rule). Àwon oba àti ìjòyè wa náà ni won ń lò láti sèjoba lórí wa. Ó pè díè kí wón tó rí wa wo.

Static Wikipedia (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -

Static Wikipedia 2007 (no images)

Static Wikipedia 2006 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu

Static Wikipedia February 2008 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu