Murtala Muhammad
From Wikipedia
A bi Murtala Muhammad ni odun 1938 o si ku ni odun 1976. Ohun ni o je olori ijoba Nigeria gege bi ologun Lati odun 1975 si 1976. Igba ti awon ologun egbe re fe gba ijoba ni won pa. Ogagun Obasanjo ti o je igbakeji re ni o bo si ori oye gege olori ijoba lati 1976 si 1979. Itan igbesi aye Murtala Muhammad ni won ko ni ede Geesi ni isale yii.