Web Analytics

See also ebooksgratis.com: no banners, no cookies, totally FREE.

CLASSICISTRANIERI HOME PAGE - YOUTUBE CHANNEL
Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions
Obafemi Awolowo - Wikipedia

Obafemi Awolowo

From Wikipedia

Obafemi Awolowo
Obafemi Awolowo

Olóògbé Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ (1909 - 1987), olósèlú, ọmọ orílẹ̀ èdè Naijiria lati ẹ̀yà Yorùbá. Awólọ̀wọ̀ jẹ́ olórí fun awon omo ile Yoruba ati okan ninu awon oloselu pataki ni orile ede Naijiria. A bi ni ojo kefa osu keta odun 1909 ni Ikenne ni ipinle Ogun. Omo agbe ti o fi ise ati ogun ise so ara re di omowe, Awolowo lo ile eko Anglican ati Methodist ni Ikenne ati ni Baptist Boys' High School ni Abeokuta. Leyin re o lo si Wesley College ni Ibadan ti o fi igba kan je oluilu Agbegbe Iwo Oorun Orile ede Naijiria lati ba di Oluko. Ni odun 1934, o di olutaja ati oniroyin. O se oludari ati alakoso Egbe Olutaja Awon Omo Naijiria (Nigerian Produce Traders Association) ati akowe gbogbogbo Egbe Awon Awako Igb'eru Omo Ile Naijiria (Nigerian Motor Transport Union).

Awolowo tesiwaju ninu eko re, o si gba iwe eri kekere ni odun 1939, ki o to lo lati gba iwe eri eko giga ninu imo owo ni odun 1944. Igba yi na lo tun je olootu fun iwe iroyin Nigerian Workers (Osise Omo Ile Naijiria). Ni odun 1940 o di akowe Egbe Odo Awon Omo Ile Naijiria (Nigerian Youth Movement) eka Ibadan, ibi ipo yi ni o ti s'olori itiraka lati se atunse Igbimo Alase Idamoran Fun Awon Omo Ibadan (Ibadan Native Authority Advisory Board) ni odun 1942.

Ni Odun 1944 o lo si ilu Londonu lati ko eko ninu imo ofin be ni o si se idasile Egbe Omo Oduduwa. Leyin igba to pari eko re ni odun 1947 o dari pada wale lati wa di agbejoro ati akowe agba fun Omo Egbe Oduduwa. Leyi odun meji, Awolowo ati awon asiwaju Yoruba yioku se idasile Egbe Oselu Action Group eyi ti o bori ninu ibo odun 1951 ni Agbegbe Iwo Oorun Ile Naijiria. Larin odun 1951-54 Awolowo je Alakoso Fun Ise Ijoba ati Ijoba Ibile, o si di Olori Ijoba Agbegbe Iwo Oorun Ile Naijiria ni odun 1954 leyin atunko Iwe Igbepapo Ati Ofin (constitution).

Gege bi Olori Ijoba Agbegbe Iwo Oorun Ile Naijiria, Awolowo se idasile eko ofe fun gbogbo odo lati ri pe moko moka gba le ka. Ni igba ti orile ede Naijiria di olominira ni ojo kinni osu kewa odun 1960, Awolowo di Olori Alatako Oselu (Opposition Leader) si ijoba Abubakar Tafawa Balewa ati Aare Nnamdi Azikwe ni Ilu Eko. Aiko enu larin ohun ati Samuel Ladoke Akintola to dipo re gege bi Olori Ijoba ni Agbegbe Iwo Oorun ni o fa jagidijagan ti o sele ni odun 1962. Ni odun yi ni osu kokanla re sini Ijoba Apapo ile Naijiria fi esun kan Awolowo pe o dote lati doju ijoba bole. Leyin igbejo to gba osu mokanla, ile ejo da Awolowo ati awon egbe oselu re mejidinlogbon lebi esun idote, won si ran won lo si atimole fun odun mewa. Odun meta pere ni o lo ni ile ewon ni ilu Calabar ti ijoba ologun Yakubu Gowon si fi sile ni ojo keta osu kejo odun 1966. Leyin eyi Awolowo di Alakoso Ijoba Apapo fun Oro Okowo. Ni odun 1979 Awolowo se idasile Egbe Oselu Imole.

Obafemi Awolowo se alaisi ni ojo aiku ojo kesan osu karun odun 1987 ni ilu Ikenne. Leyin iku Awolowo Ijoba Apapo yi oruko Ile Eko Giga Ile-Ife si Obafemi Awolowo University. Be si aworan Awolowo wa lori owo ogorun naira fun eye gbogbo ohun to se fun idagbasoke ile Yoruba ati orile ede Naijiria lapapo.

In other languages

Static Wikipedia (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -

Static Wikipedia 2007 (no images)

Static Wikipedia 2006 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu

Static Wikipedia February 2008 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu