Sikhism
From Wikipedia
AYORINDE OLUMUYIWA
SIKHISM
Sikhism jé èsìn tí ó wúlò, kò wà nínú àwon ìgbàgbó kan tàbí àheso òrò lásán, kìí se ti oní wíwá ojúbo àti sárè kiri tàbí oníkanra yogis. Òhun ni ònà ìyè tí a lè ní ìyè lé lórí gégé bí i àwòkóse. Inúkan ni ó dá lé lórí pàtó, kò sì sí ohun tó ju èdá lo tàbí ìtàn ìwásè kan tí ó simi lé, kò gbàgbó nínú èsù tàbí ángélì tàbí èmí ti òrun.
Ó jé èsín gbogbo ènìyàn tí ó lò dì sí ìlànà ìfojú àìtó àti ìsìn wò, kì í se ìgbàgbó tó sókúnkùn, ìgbóràn tó sókúnkùn sí àwon aláse gbogboogbò ni ó lòdi sí, ikú àwon olóye kò ní jé ìyè èmí náà. Ìgbàgbó kò bèrè pèlú ìfura tàbí èèwò. Èsìn yíì jé ìgbàgbó ti ìrètí àti ìmúnínúdùn, bí ó tílè jépé ó tenu mó karma, ó dá síse ìyípadà karima enìkan pèlú ore-òfé tí Guru tàbí Olórun mò, kò jásí àìnírètí àti ìparun. Ó jé èsìn àjùmòse. Ìpinnu tí sangati máa ń kí yèsí ìdánilójú oní òfi ipá (Gurmatta) Guru Gobind singh salub ní àsà ìpéjopò náà. Sikhism, èyí tí ó kéré jùlo nínú àwon èsìn lágbayé. Ó tó ogórùn márùn odún séyìn. Olùdásílè rè, Guru Nanak, ni abí ní ogórùn méfà dín ní ogbòn odún séyìn (1469). Ó tan isé iranse ‘Ek ong Kari tí ó rorùn. A jé òkan, tí adá, nípa se elédà á gbogbo èdá. Eléyìí ni igbàti India yapa nípasè Castes, egbé, èsìn tí ó yapa àti alákatakítí. Kòláàtò pèlú èsìn kankan ó sì bò wò fún gbogbo èsìn. Ó mu dájú wí pé Olórun kan ló wà ó sì pín si orísìí ònà, àti wí pé òtító ni orúko olórun (SatNam).
Àwon alátèlé Hindu àti Mùsùlùmí Guru Nanak ni ó bèrè sí ń pè é ní Sikhs (akékò). Ó kówon láti teríba níwájú Olórun nìkan, àti láti se ara won pò sí tí Guru, ìmólè òtító, tí ó mà ń ní ìtara sí Olórun, nínú ìrírí àìyapa. Nípasè òrò àti àpeere Olùkó èsìn yíì fihàn fún omo èyin rè bí ase ní iríri olórun nínú ara won, mímú won jáde láti inú òkùnkùn wá sínú ìmólè. Olùkó yíì jé onírèlè tí ó ní ìmólè òtító. Ó tako èsìn késìn, ìtàjè rúbo, egbé tíkò gúnrégé àti àìsòótó, ìkòsílè àti àgàbàgebé àti àfipá wá nnkan nípa kíkó orin ti òrun èyí tí ó bá okùn àwon tí ó ń fetísi pàdé. Orin yìí ni a tè, tí a tún ní àwòrán ìbèrè Sikhs. Ìko mímó, tí ó wà pàdà di.
GURU NANAK KONI NIPA ÒNÀ ÌGBÉ AYÉ RÈ
Láti dìde kí òrùn tó tàn, láti we aramó, sísàsàrò nípa orúko olórun àti láti kó orín Guru kí ara wón fi mó ní gbogbo ojó, kí wón sì máa rántí orúko olórún nígbàgbogbo pèlú gbogbo èmí. Amú ìpìlè èsìn yìí le le nípasè Guru Nanak tí ó sì fi ìtara tirè sínú omo èyìn kan, tí ó wá Guru èsìn yìí osi tun ton ìmólè lo sí òdò elòmíràn. Guru yìí ni a mú láti inú gbòngbò òrò ‘Gu’ tí ó túmò sí òkùnkùn tàbí àìní ìmò àti ‘Ru’ tí ó túmò sí ìmólè tàbí ìmò. Guru yíì ní ìmò òtító (olórun).
Òkòòkan Guru mewa yíì ń tóka sí àwòmóni tòrun: Guru Nanak - Ìteríba, Guru Angad-Ìgbóràn, Guru Amar Das-Ìdógba, Guru Ram Das-Guru Arja-Ìséra eni, Guru Hargobind – òdodo, Guru Har Rai-Àánú, Guru Harkrisham-ìwà mímó, Guru Tegh Bahadur-Isim, àti Guru Gobind singh ìláyà bí o ba.