Wọlé Sóyinká
From Wikipedia
Oluwole Soyinka (ojoibi 13 July 1934) je ojogbon (Professor) ninu Imo Ikowe (literature), alakosile ere ori itage (Playwright) ati akewi (poet). Omo orile ede Naijiria ni soyinka je, lati eya Yoruba. Soyinka gba Ebun Nobel ni odun 1986 fun ise owo re lori igbega imo ikowe.